Home MUSIC S.O.B – “Wagba” (Prod. By Glitz)

S.O.B – “Wagba” (Prod. By Glitz)

SOB bang in with this hot song titled WAGBA

Kindly download, comment and don’t forget to share

 

Promote Your Music, Video, Comedy Skit Here On 🇳🇬 NaijaWays 🇳🇬
Call on : +2347050263403

Wagba Lyrics

Ta lo shepe fun ori Ade..wagba
Sun inu tubu ninu aiye…….wagba
Ewure to pa shora………wagba..
Omo re Loma do pa…….wagba.
Client to ba lo mura,Is a pity aje lamba(backup)
Aje to lo fo lasaan,,ko si oju anu won ja le gba.
Aje butter fe fa igbo.X2
Ti iyare ba fi le gboX2
Idi re a yaX2
Ti iya re ba fi le moX2
Shekube felo si school
Oni ohun fe lo kawe
Omo ase to ja,fi school le ko lo join Marley.
Sheybi virgin lo pe raX2
Naira Marley wa lon pe eX2
ki lo wa she Lori bedX2
Mama ma dun bi ewureX2
Sheke sheke Mami
Mami Mami
Sheke sheke Mami
Mami mami.

Suliamon lo so agboleX2
Oni ohun fe lo lota
Igba to pada wa le.
Oma ti gboja lura.
Ika lo pa de ika.
Ohun ni ika de fi jise ika
Ika ti fun ika loyun
Ohun ni ika de fi bimo ika.
Omo ase jjc…..wagba
Yahoo boi to Sabi…..wagba.
Arugbo ton sho ge….wagba
Eyin omo no salary….wagba.
Eyin omo no condom…wagba.
Eyin omo royal boiz….. wagba.
Set awon my bestie …wagba.q
Awon oloja fun oja…wagba.
Awon omo ejigbo……..wagba.
Set awon my sister……….wagba.
Set awon small baddo……wagba.
Set awon chabinsmart…….wagba.
Set awon no bet gang……..wagba.
Eyin omo ikotun………wagba.
Eyin omo agege…….wagba.
Set awon small doctor….wagba.
Awon omo no manners…. wagba q
Set awon s.o.b….wagba……

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here